EDE YORUBA JS3 OSE KEJI

Report
Ni oro tabi akojopo oro ti a le ri ni ipo oluwa tabi ipo abo ninu
gbolohun.
Bi apeere:
Bolu ti jade ile-iwe.
Mo je ibepe.
Iwo feran ise.
IHUN APOLA-ORUKO.
1. Apola-oruko eleyo oro kan.
a.
Oro-oruko kan ni ipo oluwa tabi abo.
bi apeere:
Ade je isu.
Sade pa ejo.
Ibadan ni mo lo.
b. Oro aropo-oruko kan ni ipo oluwa tabi abo.
Bi apeere:
Mo jeun.
E wa mu omi.
Akin ti ri won.
d. Oro Aropo-afarajoruko ni ipo oluwa.
Bi apeere:
Emi ko mo.
Oun ni o fe ri.
Awon omo n ko?
2. Apola-oruko ti o je akojopo oro. Oro-oruko akoko ni o maa n je ori
nigba ti awon yooku yoo je eyan.
Bi apeere:
Ise oluko wu mi.
ori
eyan
2. Ade oba ni mo de.
Ori
eyan
3. Mo lo si Oja ale
Ori
eyan
Ise Apola-oruko :Ise meteeta ti oro-oruko n se ninu gbolohun ni apolaoruko n se.
Awon ni;
Oluwa:
Ade jeun.
Tolu pa eja.
Isu ni mo je.
Abo:
Iya agba we gele.
Bisi je isu.
Mo lo si Eko.
Eyan:
Ade olobe ni o wa.
Aja Oba ni mo pa.
O de ade Oba.
Ise asetilewa.
Iru ise wo ni apola-oruko ti a fala si n se ninu
gbolohun wonyii:1. Olu sun.
2. Sade pon omi.
3. Ise agbe dara.
4. Oluko n pe wa.
5. Wa ri mi ni ale.

similar documents